Refrain:
Mo ti ní Jésù (I have Jesus)
Mo ti l’Olúwa (I belong to the Lord)
Ayé ò lè gbà mí lọ́wọ́ Rẹ̀ o (The world cannot separate me from Him)
Mo ti l’Olúwa (I belong to the Lord)(Repeat)
Spoken:“Nitori na ma beru, emi wa pelu re. Ma se jeje aya, ma fo.” Emi na gbohun re, “Emi o fun wo lagbara, Emi o si ran lowo”(“Therefore, do not be afraid, for I am with you. Calm Your heart, do not be afraid.” I also heard His voice: “I will give you strength, I will help you”)
(Refrain)
Spoken:If not for God who has been for you and I, what would have been our lot? Thank You Jesus for being a loving Father.
Èmi ti Jẹ́ Olúwa, tó ń tọ́ iwájú mi ní gbogbo ìgbà (I have always kept the Lord beforeme) Torí ó wà ní apá ọ̀tún mi (Because He is at my right hand)
A ò lè ṣí mi nípò (I cannot be removed from my position) Ìbẹ̀rù kò sí, ìfoyà kò sí (There is no fear, there is no dread) Torí mo ní Ọ ní Bàbá, Ọ (Because I have You as my father) Mo ti l’Olúwa (I belong to the Lord) (Repeat)
(Refrain)
Bí ẹnìyàn bá yọ̀wọ́, kì í yọ̀wọ́ (When people let go, He won’t let go)
Bí ẹnìyàn bá kọ̀ ní, kì í kọ̀ ní (When people forsake, He will not)
Níní tí mo ní ló lọ́kàn mi ṣe báalẹ̀ (Because I have You, I have peace of mind)
Abánimúlẹ̀, má dáni (The One who does not break His covenant) (Repeat)
(Refrain)
Ohun àjẹ́gẹ́ kò lè gbà ọ́ lọ́wọ́ Bàbá yẹn (Strange things cannot separate you from that Father)
Ọ̀rọ̀ òdì kò lè gbà ọ́ lọ́wọ́ Bàbá yẹn (Contradicting words cannot separate you from that Father)
Ègún àti èpè ilé wa kò lè gbà ọ́ lọ́wọ́ Rẹ̀ o (Curse and evil utterance in our family cannot separate us from Him)
Ohun ló já wa gbà lọ́wọ́ ogun (He is the one who fought to rescue us from battles)
Abánimúlẹ̀, má dáni (The Covenant Keeper who never fails)
Bí ẹnìyàn bá yọ̀wọ́, kì í yọ̀wọ́ (When people let go, He won’t let go)
Bí ẹnìyàn bá kọ̀ ní, kì í kọ̀ ní (When people forsake, He will not)
Níní tí mo ní ló lọ́kàn mi ṣe báalẹ̀ (Because I have You, I have peace of mind)
Abánimúlẹ̀, má dáni (The One who does not break His covenant) (Repeat)
Get this dross out
Oh, burning fire, inside my heart and mind
I need them all to burn
Carried for too long
I surrender to Your furnace
Purify my heart, oh fire
Oh fire, burn! Burn
Fire burn
Oh fire burn
Fire burn
Ga-a mu (Here we are)
Mun taru, a gare ka (Gathered before You)
Da hanu, a sama (With hands lifted high)
Ka sauko, da ruhun ka (Bring down your Spirit)
Kamar wuta (Like fire)(Repeat)
Purify my heart oh fire
Purify my heart oh fire
Get this dross out
Oh, burning fire
Yeah, inside my heart and mind
I need them all to burn
Carried for too long
I surrender to your furnace
Purify my heart oh fire
Ga-a mu (Here we are)
Mun taru, a gare ka (Gathered before You)
Da hanu, a sama (With hands lifted high)
Ka sauko, da ruhun ka (Bring down your Spirit)
Kamar wuta (Like fire)(Repeat)