Mo Ti Ni Jesu (I have Jesus) Lyrics by Mista Olamilekan and Adeyinka Alaseyori

Leave a comment

(Languages: Yoruba, English)

Refrain:
Mo ti ní Jésù (I have Jesus)
Mo ti l’Olúwa (I belong to the Lord)
Ayé ò lè gbà mí lọ́wọ́ Rẹ̀ o (The world cannot separate me from Him)
Mo ti l’Olúwa (I belong to the Lord) (Repeat)

Spoken: “Nitori na ma beru, emi wa pelu re. Ma se jeje aya, ma fo.” Emi na gbohun re, “Emi o fun wo lagbara, Emi o si ran lowo” (“Therefore, do not be afraid, for I am with you. Calm Your heart, do not be afraid.” I also heard His voice: “I will give you strength, I will help you”)

(Refrain)

Spoken:If not for God who has been for you and I, what would have been our lot? Thank You Jesus for being a loving Father.

Èmi ti Jẹ́ Olúwa, tó ń tọ́ iwájú mi ní gbogbo ìgbà (I have always kept the Lord before me)
Torí ó wà ní apá ọ̀tún mi (Because He is at my right hand) 
A ò lè ṣí mi nípò (I cannot be removed from my position)
Ìbẹ̀rù kò sí, ìfoyà kò sí (There is no fear, there is no dread)
Torí mo ní Ọ ní Bàbá, Ọ (Because I have You as my father)
Mo ti l’Olúwa (I belong to the Lord) (Repeat)

(Refrain)

Bí ẹnìyàn bá yọ̀wọ́, kì í yọ̀wọ́ (When people let go, He won’t let go)
Bí ẹnìyàn bá kọ̀ ní, kì í kọ̀ ní (When people forsake, He will not)
Níní tí mo ní ló lọ́kàn mi ṣe báalẹ̀ (Because I have You, I have peace of mind)
Abánimúlẹ̀, má dáni (The One who does not break His covenant) (Repeat)

(Refrain)

Ohun àjẹ́gẹ́ kò lè gbà ọ́ lọ́wọ́ Bàbá yẹn (Strange things cannot separate you from that Father)
Ọ̀rọ̀ òdì kò lè gbà ọ́ lọ́wọ́ Bàbá yẹn (Contradicting words cannot separate you from that Father)
Ègún àti èpè ilé wa kò lè gbà ọ́ lọ́wọ́ Rẹ̀ o (Curse and evil utterance in our family cannot separate us from Him)
Ohun ló já wa gbà lọ́wọ́ ogun (He is the one who fought to rescue us from battles)
Abánimúlẹ̀, má dáni (The Covenant Keeper who never fails)

Bí ẹnìyàn bá yọ̀wọ́, kì í yọ̀wọ́ (When people let go, He won’t let go)
Bí ẹnìyàn bá kọ̀ ní, kì í kọ̀ ní (When people forsake, He will not)
Níní tí mo ní ló lọ́kàn mi ṣe báalẹ̀ (Because I have You, I have peace of mind)
Abánimúlẹ̀, má dáni (The One who does not break His covenant) (Repeat)

(Refrain)

(Spoken)

(Refrain)

Jowo (Please) Lyrics by Adeyinka Alaseyori ft Ofemismile

Leave a comment

(Sung in Yoruba)

Gbà mí, Olórun gbà mí! (Save me, Oh God rescue me!)
Gbà mí, Olórun gba mí! (Save me, Oh God save me!)
Gbà mí, Olórun gba mí, jà mí gbà o! (God fight for me and rescue me) (Repeat)

Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́! (Please, God please)
Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́ (Please, Oh God please)
Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́, má pàdà o! (Lord, please do not turn away from me) (Repeat)

Ma toju mi (Keep caring for me)
Ma yowo lori mi (do not withdraw Your Hand from me)
Ma gba fun mi lo (Keep interceding on my behalf)
Ma yowo lori mi, Olorun (Oh God do not withdraw Your Hand from me)
Iwo to mi lowo de ibi ti mo de loni o
(You who have helped me on my journey until today)
Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́, má pàdà o! (Lord, I plead, do not turn away from me)

Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́! (Please, God please)
Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́ (Please, Oh God please)
Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́, má pàdà o! (Lord, please do not turn away from me) (Repeat)

Gbà mí nínú túbú ayé wa (Deliver me from this life’s prison) x2
Gbà mí nínú túbú ilé wa (Deliver me from the prisons in my household)
Túbú tá ti mí mọ́ o, gbà mí o (Save me from the prison that has held me captive)
Mi ò lágbára, mi ò lè yán o (I have no strength, I’m alone)
Mi ò lágbára, mi ò lè yán o (You are the only One I have)
Aláàánú mi, ṣàánú mi (Merciful One, have mercy on me)
Mo fe kuro ninu tubu ile wa (I want to escape from the prison in my household)
O de gba mi o (Please save me)
Ẹ kún yìí, ẹ kún ogo ni (This is a cry for glory)
Ẹ kún ìí, ẹ kún àánú ni (This is a cry for mercy)
Dákẹ́, gbà mí lágbàtàn o (Please save me completely)
Jẹ́ kí n ṣe ohun tó lè, nínú ìran wa
(Let me accomplish what has been impossible in my lineage)
Ràn mí lọ́wọ́, Jẹ́ kí n ṣe ohun tó lè, nínú ìran wa
(Help me accomplish what has been impossible in my lineage)
Bí àwọn egungun gbígbẹ́ bá lè yè (If dry bones can become flesh again)
Jẹ́ kí ayé tèmí náà yè (Then let my own life live again)

Má kọjá mi, Olùgbàlà (Do not pass me, Savior)
Bó ṣe ń rìn láàárín àwọn ènìyàn wọ̀nyí (As You move among these people)
Má kọjá mi, Olùgbàlà (Do not pass me, Savior)
Ó ń rìn níbí Olúwa, má jẹ́ kí ó já mi (You are moving here Lord, do not pass me)
Èyí tí mo fi omijé bẹ̀rẹ̀ nìkọ̀kọ̀ (The things I secretly asked for in tears)
Fi àánú dá mi lóhùn ní gbangba (Answer me publicly with mercy)
Fi ẹ̀rín sí èmi náà l’ẹnu (Put laughter in my lips as well)
Mo ti ń bá wọn yọ̀ yọ̀…, Olórun ayọ̀ mi (I have been rejoicing with them, my God of Joy)
Ṣé òní ni ọjọ́ tí máa yọ̀ fún èmi náà (Make today my day of joy as well)
Ẹ̀gàn yìí pọ̀ jù (The affliction is too much)
Àwọn tí ó tó mi gan-an sọ̀rọ̀ sí mi (Even those who are not up to me speak against me)
Àwọn tí mo ṣe jùmọ̀ lóló wọn advisẹ̀ mi (Those who I am better than are now advising me)
God help me consciously; lift me consciously; heal my land
Tí ilé tí mo gà gbìn tí ó bá jẹ́ ilé tó lẹ́ṣọ̀ (If the land is not fertile)
Olórun mi, mú irúgbìn kúrò lórí ìyẹ̀ yìí (My God, remove that seed from the land)
Kò gbìn mí sórí ilé tó lẹ́ṣọ̀ (Plant me in fertile and fruitful land)
Fi olùrànlọ́wọ́ ayànmọ́ yìí mí ká (Surround me with divinely appointed helpers)

[Spoken]

Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́! (Please, God please)
Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́ (Please, Oh God please)
Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́, má pàdà o! (Lord, please do not turn away from me) (Repeat)

[Spoken]

Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́! (Please, God please)
Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́ (Please, Oh God please)
Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́, má pàdà o! (Lord, please do not turn away from me) (Repeat)

[Spoken/Prayer]

Gbà mí, Olórun gbà mí! (Save me, Oh God rescue me!)
Gbà mí, Olórun gba mí! (Save me, Oh God save me!)
Gbà mí, Olórun gba mí, jà mí gbà o! (God fight for me and rescue me) (Repeat)

Gbat’Iwo ba n p’elomiran (When on others thou art calling)
Ma se koja mi (Do not pass me by) (Repeat)

Gbà mí, Olórun gbà mí! (Save me, Oh God rescue me!)
Gbà mí, Olórun gba mí! (Save me, Oh God save me!)
Gbà mí, Olórun gba mí, jà mí gbà o! (God fight for me and rescue me) (Repeat)

Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́! (Please, God please)
Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́ (Please, Oh God please)
Jọ̀wọ́, Olórun jọ̀wọ́, má pàdà o! (Lord, please do not turn away from me) (Repeat)

Mo Moore (I am Grateful) Lyrics by Adeyinka Alaseyori ft Elijah Daniel, Magpsalms, Oladosu Twins, Magdalene Whowha, Iyanu Ileyemi, Ernieola Oluso

1 Comment

(Languages: Yoruba, English)

Refrain:
Olu, Olu, Oluwa o (Mighty, Mighty God)
Olu, Olu, Oluwa o (Mighty, Mighty God)
Mo mo’ore o, mo mo’ore (I am grateful, I am grateful)
Ibi obamide looni o (Where You’ve brought me to today)
Anu nla ni (It is Great Mercy) (Repeat)

Lord, I’m grateful in so many ways
Emaseun o, modupe o (Thank You, I’m grateful)
Mo mo’ore, o mo mo’ore (I am grateful, I am grateful)
Ibi obamide looni o (Where You’ve brought me to today)
Anu nla ni (It is Great Mercy)

(Refrain)

For everything You’ve done, Lord I’m grateful
For Your Grace and mercies and Your blessings too
I’m grateful Lord Jesus, I’m grateful
Tori bo se gbe mi loju mejeji o (For the way You carry me in all ways)
Anu nla ni (It is Great Mercy)

(Refrain)

Emi mo’ore Jesu laye mi (I know of Your Goodness in my life, Jesus)
Ore riri je, riri mu, ore igbagbogbo o
(Visible blessings, to eat, to drink and constant blessings)
Emi mo’re, mo mo’ore (I am grateful, I am grateful)
Ibi obamide looni o (Where You’ve brought me to today)
Anu nla ni (It is Great Mercy)

(Refrain)

Oluwa, Oluwa, mo mo’ore (Lord, Lord, I’m grateful)
Oun gbogbo ti mo la koja (All that I’ve been through)
Ko da ise re duro (Did not stop Your work)
Okan mi mo’ore, moresi ayo (My heart is grateful, I receive good news)
Anu re losun mi debi o (Your Mercy brought me this far)
Mo mo’re (I’m grateful)

(Refrain)

Ibi esin mi de (Where You’ve brought me)
Mio mo pe mo le de be o (I didn’t know I could get there)
Ibi e ba se de, lomu mi yin o Oluwa o (What You’ve done in my life, leads me to praise You)
Okan mi mo’ore loni o (My heart is grateful today)
Ibi obamide looni o (Where You’ve brought me to today)
Anu nla ni (It is Great Mercy)

(Refrain)

Olu, olu, Oluwa o (Mighty, Mighty God)
Abba, I’m grateful for everything You are to me
Okan mi pongbe fun o, Eledumare mo mo’ore (My hear Longs for You Creator, I am grateful)
Ibi obamide looni o (Where You’ve brought me to today)
It’s by Your Grace and Mercy

(Refrain)

Aye ti lekun (When the world shuts its doors)
Iwo lobami si (You are the one who opened them for me)
Aye ma ti lekun (When the world shuts its doors)
Iwo lobami si (You are the one who opened them for me)
Oja ogo to ro pe ko le ta (The Glory that seemed impossible to sell)
Iwo lo kowo le (You’re the one who made it valuable)
Mo mo’ore o, mo mo’ore (I am grateful, I am grateful)
Ibi obamide looni o (Where You’ve brought me to today)
Anu nla ni (It is Great Mercy) (Repeat)

(Refrain)

Se ta aanu ni ton pa idajo re (It’s Mercy that cancels judgement)
Ni mo fe wi (That’s what I want to say)
Ojo iranwo, ton nro, tio le da mo (The rain of help that can never stop)
Mo mo’ore owo to ngbe mi tio jen jabo (I’m grateful for the hand that lifted me and never let me fall)
Ibi obamide looni o (Where You’ve brought me to today)
Asiri mi bo (My secret is covered) (Repeat)

(Refrain)

Oluwa, Oluwa, mo mo’ore (Lord, Lord, I’m grateful)
Gbogbo ilakoja ti mo lakoja anu re (All the trials I’ve gone through were by Your mercy)
Ko da ise re duro (Did not stop Your work)
Okan mi mo’ore, moresi ayo (My heart is grateful, I receive good news)
Anu re lo gbe mi debi o (Your Mercy brought me this far)
Mo mo’re (I’m grateful)

(Refrain)

Ibi esin mi de (Where You’ve brought me)
Mio mo pe mo le de be o (I didn’t know I could get there)
Ibi e ba se de, lomu mi yin o Oluwa o (What You’ve done in my life, leads me to praise You)
Larin opo eniyan mo’more mo’more (In the midst of multitudes, I’m grateful)
Ibi obamide looni o (Where You’ve brought me to today)
Asiri mi bo (My secret is covered)

(Refrain)

Spoken:
Ah Olorun, a se bo se tobi to re! O de mu asaye mi omo talaka, o de so mi di ogo agbaye
(Ah, My God, How magnificent are You! You took away the shame of the poor, You made me global)

Bin ba da ke lai so ohun kohun (If I kept silent and said nothing)
Olorun mo ma mo’ore (God, I’m still grateful)
Bomi ba da loju mi lai da ke (Even when my tears continuously run from my eyes)
Mo fin san ore mi (I use them to thank You)
Daddy mi mo’more ibi to tin mu mi bo, ibi omabide, (Daddy, I’m grateful for where You’ve brought me)
Ibi otimeleyin lowo lowo de anu nl ni (Where I stand now, is great Mercy)

(Refrain)

Emi mo’ore Jesu laye mi (I know of Your Goodness in my life, Jesus)
Ore riri je, riri mu, ore igbagbogbo o ni se (Visible blessings, to eat, to drink and constant blessings)
Mo’re, mo mo’ore (I am grateful, I am grateful)
Ibi obamide looni o (Where You’ve brought me to today)
Anu nla ni (It is Great Mercy)

(Refrain)

Oluwa, Oluwa, Oruko re ti niyi to ni gbogbo aye (How Great is Your Name in all the earth)
Iwo to gbe ogo re ka ori awon orun, iwo mo nki
(You who spread Your Glory across the heavens, I greet You)
Mo mo’ore owo re yi o, tio dawo duro (I’m grateful for the Hand that didn’t stop)
Ibi obamide looni o (Where You’ve brought me to today)
Asiri mi bo (My secret is covered)
Ohun to lo ma pa e ko ka e (What was meant to kill You did not)
Ohun to lo ma gbe e mi, o gbe e mi (What was meant to swallow You did not)
Sebi iwo lo duro ti aye nseere (You stood when life questioned:)
“Se oun ni oun ko o?”(“Is this not the same person?”)
Yika Mo’ore, osomi loruko tuntun (Yinka is grateful, You gave me a new name)
Ibi obamide looni o (Where You’ve brought me to today)
Won fi oruko omo pe emi na o (I’m now called my child’s name)

(Refrain)

Gbobgbo wa, lo se wa lohun elo (You made us all instruments)
Iyen si ola re (And it is for Your glory)
Aye wa npolongo iwa laye re, eje asope (Our lives proclaim Your nature in our lives)